Físíksì - Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́ Jump to content

Físíksì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Físíksì (lati inu Ìmọ̀ aláàdánidá) tabi Fisiki (Physics) jẹ́ ìmọ̀ sáyẹ́nsì tí ó ń ṣe ìwádí èlò ati awon okun ti won n je sise akiyesi ninu àdánidá.

Awon onímọ̀ aláàdánidá n se iwadi isise ati awon ohun-ini eda aye to yi wa ka lati àwọn ẹ̀yà ara ti won n se gbogbo awon elo ti a mo (Ìmọ̀aláàdánidá ẹ̀yà ara, particle physics) titi de bi àgbàlá-ayé se n wuwa bi odidi kan (ìmọ̀ìràwọ̀títò astronomy, ìmọ̀ìdáyé cosmology).

Ise imo aladanida ni lati wa awon ofin ijinle ti gbogbo awon ohun aladanida n tele.

Ko si iye igbedanwo to le fi han pe iro mi je tito, sugbon igbedanwo kan pere le fihan wipe o je aitoAlbert Einstein